KCC jẹ iṣẹ ṣiṣe to ga ati chaini gbogbo eniyan ti ko ni oludari ti a ṣe nipasẹ KCS ati awọn olufẹ KuCoin.
Aa se lori go-ethereum nitori lati pese awọn ara adugbo pelu bulokuchaini to yara julọ, irọrun ati owo kekere fun iriri awon eniyan.
KCC yoo ni awọn ohun wọnyi:
- Ni ibamu ni kikun pẹlu Ethereum ati awọn adehun to jafafa ti ERC-20, pẹlu owo ijira ti o kere;
- KCS yoo je ohun elo ati tokeni abinibi fun KCC ati pe a le loo ni sisanwo gassi;
- Àkọsílẹ ni gbogbo iṣẹju -aaya meta jeki idunadura yara ati ki ise chaini ga;
- Ẹri ti Alaṣẹ ti a tojupamo Proof of Staked Authority (PoSA) algorithm ipohunpo, ise to ga, aabo to peye ati iduroṣinṣin.
Iṣẹ: Lati jeki iyara de ba awon ohun iwulo kakiri agbaye laisi won aala.
- KCC ko ni fowosi ise pasipaaro nitoripe gbogbo ise ni o je kiko lati owo awon ara agbegbe. Nitorinaa, KCC oni lodidi fun ini lara ti awon ise yi muwa. Ati pelu, KCC ko sise bi asoju ise onibara fun awon aksanse ise wonyi.
- Ṣaaju ki o to towobo awọn iṣẹ eyikeyi ni awọn aaye ti o batan mo owo afefe tabi DeFi, jọwọ kọkọ ṣe iwadii tirẹ finifini.
- Gbogbo eniyan ati awọn olupilẹṣẹ lo le kọ dAppu ni testneti KCC lẹhin ti wan le gbe si mainneti lofe.
- Jọwọ da agbegbe testneti mo yato si ti agbegbe mainneti. Awọn ohun ini to wa lori testneti ko ni iye, nitorina jowo soora fun jibiti owo afefe.
- KCC yoo kede aṣẹ, igbega ati ifowosowopo nipase awon netiwoki awujo tire ti a fi onte lu, jọwọ sayewo alaye ti a fi onte lu ki o si yago fun awon ebu ayelujara.
- Jọwọ ri daju pe owa ni ayelujara ti a fi onte lu lati yago fun pipadanu kokoro ikoko re.
Olumulo mi owon (ti a tọka si nibi pe “iwọ”):
KCC (eyiti a tọka si nibi pe “KCC” tabi “awa”) jẹ chaini ti ko ni oludari ti gbogbo eniyan. Awọn Difelopa kakiri agbaye le ko awọn ohun elo ranṣẹ sori KCC, gbogbo awọn olumulo le ka, ranṣẹ ati ṣowo lori KCC. Nitori awọn ohun ti aisi oludari, a nfi eyi ran yin leti awọn eewu ti DAPPu ẹni-kẹta jẹ nitele:
- Ṣaaju ki o to ṣiṣẹ lori eyikeyi pepe, apamọwọafefe tabi DAPPu ẹni-kẹta, jọwọ koko ṣe iwadii re;
- Boya o kopa ni tabi lo DAPPu lori KCC nipasẹ eyikeyi pẹpẹ iṣowo eyikeyi tabi apamọwọafefe, o jẹ isesi rẹ ati pe a ko sope ko lo;
- A ko ṣe iduro fun ayewo eyikeyi DAPPu ẹni-kẹta, tabi ṣe a ṣe adehun ati idaniloju eyikeyi lori ijẹrisi, isedeede, otitọ, igbẹkẹle, didara, pipe, iduroṣinṣin ati isise lasiko ti imọ-ẹrọ ati alaye ti o wa ninu awọn iṣẹ rẹ;
- O yẹ ki o foriru gbogbo awọn ojuse ti o ba wa lati lilo eyikeyi awọn iṣẹ DAPPu ẹnikẹta funrararẹ;
- Boya awọn iṣẹ DAPPu ẹnikẹta pade faramo ofin, awọn ilana tabi awọn ilana ti o yẹ ti agbegbe re, jọwọ ṣe idajọ ati agbeyewo tirẹ. A ko pese agbeyewo eyikeyi, jọwọ rii daju pe o faramọ awọn ofin ti agbegbe rẹ;
- Iwọ ati DAPPu ẹni-kẹta yoo gba awọn ojuse ti eyikeyi awọn wahala ti o jọmọ lilo DAPPu ẹni-kẹta, pẹlu ṣugbọn kii ṣe opin si awọn ọran ofin, awọn ọran gbese adehun, awọn adanu ọrọ aje, ati bẹbẹ lọ., KCC kii yoo ṣe iduro fun wọn;
- Ayafi to ba fun wa laṣẹ lati ṣe bẹ, KCC kii yoo pin alaye tiẹ pẹlu eyikeyi DAPPu ẹni-kẹta. To ba fun wa laṣẹ lati pin alaye naa, gbogbo awọn gbese ofin ati awọn ariyanjiyan nipase wiwole DAPPu ẹni-kẹta si alaye tiẹ ni yoo gba nipasẹ iwọ ati DAPPu ẹni-kẹta.
- KCC ko lẹtọ lati fun ọ ni alaye awon difelopa DAPPu ẹni-kẹta ayafi ti wọn ba gba lati ṣe bẹ. A yoo ṣe iranlọwọ ninu ọro yii sugbon a ko le fowosoya pe o le gba alaye naa.
Ni ipari, a nilo lati ran e leti pe a ko ṣeduro tabi ran e lati lo eyikeyi iṣẹ DAPPu ẹni-kẹta.
Awọn olumulo agbegbe le lo eyikeyi apamọwọafefe to nibaramu pelu Ethereum lati se atunto pẹlu awọn paramita nẹtiwọọki KCC, bii metamask, myetherwallet, imtoken, TokenPocket abbl.
Oruko Chaini: KCC-MAINNET
Idanimo Chaini: 321
Aami: KCS
RPC Ayelujara: https://rpc-mainnet.kcc.network
Oluwakiri Ayelujara: https://explorer.kcc.io/en
WebSocket RPC Ayelujara: wss://rpc-ws-mainnet.kcc.network
Oruko Chaini: KCC-TESTNET
Idanimo Chaini: 322
Aami: KCS
RPC Ayelujara: https://rpc-testnet.kcc.network
Oluwakiri Ayelujara: https://scan-testnet.kcc.network
WebSocket RPC AyelujaraL: wss://rpc-ws-testnet.kcc.network
Osooro Ayelujara: https://faucet-testnet.kcc.network (fun ayewo lasan ni, ko ni iye)
O le losi taara si https://github.com/kcc-community/kcc/releases lati ṣe igbasilẹ ẹya tuntun faili alakomeji。
Tabi o le lo si https://hub.docker.com/r/kucoincommunitychain/kcc si imuṣiṣẹ to yara ati idanwo。(Bii o ṣe le lo Docker?)
- Linux tabi Mac
- golang >= 1.13
- git
bi o ṣe le ṣe igbasilẹ ati fifi golang sori ẹrọ
git clone -b kcc --single-branch https://github.com/kcc-community/kcc.git
cd kcc
make geth
Awọn asia laini aṣẹ jẹ iru ti go-ethereum, o le lo ./build/bin/geth --help
fun gbogbo awọn aṣayan laini aṣẹ, bi ./build/bin/geth --testnet
lati kpa ninu Testneti. Sọra: Lo ẹya "geth" pato to wa ni ./build/bin/geth
.
O le lo https://hub.docker.com/r/kucoincommunitychain/kcc lati yara mu ṣiṣẹ ati danwo.
4 core cpu
8g memory
200G and scalable SSD
public ip with TCP/UDP:30303 open
./geth #Mainneti
./geth --testnet #Testneti
awon asayan to wulo:
/data/kcc/geth \
--datadir /data/.kcc/testnet \ #your data dir
--testnet \ #Testnet
--http \ #http rpc
--http.addr 0.0.0.0 \ #http rpc bind address
--http.vhosts * \ #vhosts
--http.corsdomain * \ #http corsdomain
--ws \ #ws rpc
--ws.addr 0.0.0.0 \ #ws rpc bind address
--syncmode full \ #syncmode
--gcmode archive #gcmode
O si le lo nohup
,supervisor
,systemd
lati se ise ati sakoso geth
labele.
O le lo awọn SDK wọnyi lati ba nodu KCC rpc soro.
- Js: web3.js Ethereum JavaScript API
- Java: web3j Web3 Java Ethereum Ðappu API
- PHP: web3.php Atokun php lati ba bulookuchaini Ethereum soro ati awon ayika re.
- Python: Web3.py Ibi ipamo Python lati ba Ehereum soro, nipasẹ atileyin web3.js.
- Golang: go-ethereum
KCC gbe ilana iṣọkan PoSA jade, eyiti o ṣe ẹya awọn owo isowo kekere, idaduro isowo kekere, iṣọkan idunadura giga, ati atilẹyin fun awọn afọwọsi mokandinlogbon.
PoSA jẹ apapọ PoA ati PoS. Lati di alafọwọsi, o nilo lati koko fi igbero silẹ ki o si duro de awọn alafowosi miiran lati dibo lori rẹ. Lẹhin ti die le ninu idaji wọn ba ti dibo, iwọ yoo ni ẹtọ lati di alafọwọsi. Eyikeyi adirẹsi ni anfani lati sokowo pelu adirẹsi miiran to peye lati di alafọwọsi, ati lẹhin awọn ipo awon onisowo ipamo alafowosi na bawa ni mokandinlogbon to siwaju, yio je alafowosi to laapon ni epochi to n bo.
Gbogbo awọn alafowosi to laapon ni a paṣẹ fun ni ibamu si awọn ofin ti a ti yan tẹlẹ ki o yipada si awọn bulọọki mi. Ti alafowosi ba kuna lati maini bulooki kan lasiko, awon alafowosi to laapon ti won ko kopa tele n/2 (n je iye awon alafowsi to laapon) awon bulooki ma se ifilole aileto. O kere ju n/2+1 awọn alafọwọsi to lapon n ṣiṣẹ daradara lati ri daju pe ise bulookichaini n lo daradara.
Iye iṣoro ti bulọki jẹ meji nigbati a ba se bulooki naa ni ilana ti o to ati ookan nigbati a ba se bulooki na na ilana ti ko to. Nigbati eka ti bulookichaini ba waye, bulookichaini yio yan eka ti o bamu ni isoro akopo to poju.
KCC ti ṣe awọn adehun meta ti a ṣe sinu adehun fun PoSA ninu faili ipilẹṣẹ.
Koodu orisun ti awọn adehun wọn yẹn wa lati eka Heco, o le wa wọn nibi: https://github.com/kcc-community/kcc-genesis-contracts。
Isakoso ti awọn alafawosi lọwọlọwọ je sise nipasẹ awọn adehun eto.
- Igbero to wa fun ṣiṣakoso iraye si awọn alafọwọsi ati ṣiṣakoso awọn igbero alafọwọsi ati awọn ibo.
- Awọn alafowosi to wa fun iṣakoso ati ipo awọn alafọwọsi, fifi isowopamo ati yiyo isowo, pinpin awọn ere bulọki, abbl.
- Ijiya to wa fun ijiya awon isowo to lodi si awon alafowosi to laapon ti won ko sise daradara.
Awọn adehun eto ipe Bulookichaini :
- Ni ipari ti bulọki kọọkan, a pe adehun awọn alafọwọsi ati pe owo gbogbo owo ninu bulooki naa ni a o pin fun gbogbo alafowosi to laapon.
- Adehun ijiya naa ni a o pe lati fi iya jẹ alafowosi nigbati alafowosi naa ko ba sise daradara.
- Ni ipari epochi kọọkan, a o pe adehun alafowosi lati se imudojuwon awon alafowosi to laapon, gegebi opo naa.
O le pe ọna stake
ninu adehun validator
fisowopamo fun eyikeyi alafowsi, iye to keere ju fun ifowopamo fun alafowosi kookan ni mejilelogbonKCS.
Ti o ba fẹ unstake
KCS rẹ, o nilo lati pe ọna unstake
ninu adehun validator
,
ki o si duro fun bulooki 86400(ojo meta), ki o to pe ona withdrawStaking
ninu adehun validator
lati je ki iye yen wan fun lilo.
Nigbakugba ti a ba ri alafowosi ti ko maini bulooki be ase pese, adehun ijiya ni adase yio je pipe nipari bulooki naa ati pe alafowosi naa yio je kika. Nigbati onka ba de merinlelogun, gbogbo owo -towọle ti alafọwọsi ni iya yio je. Nigbati onka naa ba de mejidinladota, a o yọ alafowosi na kuro ninu ninu atokọ ti awọn alafowosi ti n ṣiṣẹ, ati pe alafọwọsi naa ti di alaimọ.
Eyikeyi imọran, awọn isoro ati ijiroro jẹ itẹwọgba.
Ti o ba ni isoro lori iṣẹ akanṣe pataki, jọwọ gbe lọ si oju-iwe issue
ti iṣẹ akanṣe Pataki yii.
Awọn igbero Ilọsiwaju KCC
Awọn igbero Ilọsiwaju KCC (KIPs) ṣe apejuwe bose ye ki nkan wa fun pẹpẹ KCC, pẹlu chaini, DEX, ati awon dAppu.
Idi fun ilana yii ni lati rii daju awọn iyipada si KCC jẹ titan ati iṣakoso to dara.
AYELUJARA:https://github.com/kcc-community/KIPs
1.Kini ọna iṣọkan ti KCC?
KCC nlo ilana iṣọkan ti PoSA, ti o ni ifihan owo kekere, iṣẹ giga ati bulooki sise to duroṣinṣin, ni atilẹyin nodu awọn alafowosi mokandinlogbon;
2.Bo se le di nodu alafowosi KCC?
Lati di alafowosi, o nilo lati ṣẹda nodu ati ki o fi igbero silẹ, ki o duro ki awọn alafowosi miiran lati dibo. Lẹhin ti o ba gba ibo die le ni idaji alafowosi, iwo naa yio leto lati di alafowosi. Adirẹsi eyikeyi le fiisowopamo si adirẹsi ti o yẹ lati di alafọwọsi. Lẹhin ti ipo isowopamo ba ti wa ni mokandinlogbon akoko, alafowosi naa yi kopa ninu epochi ti o n bo.
3.Ṣe KCC ṣe atilẹyin fun EVM?
KCC ṣe atilẹyin ni daada fun EVM ati pe o jẹ ọrẹ fun awon difelopa Ethereum.
4.Kini SDK ti KCC n lo?
KCC wa ni ibaramu gan pupo pẹlu Ethereum, nitorinaa a n lo sdk ti Ethereum bii web3js, web3j, abbl.
5.Mo fẹ ṣe awọn iṣẹ ati awọn idanwo lori testneti KCC. Nibo ni mo ti le gba awọn tokini idanwo?
O le lo si faucet testneti wa: https://faucet-testnet.kcc.network.
6.Bi a se le fi awon adehun nodu pamo?
Awọn eyan le pe ọna atifiowopamo ti adehun alafọwọsi lati fi owo pamo si eyikeyi nodu. Iye ti o kere julọ fun alafowosi kọọkan ni mejilelogbon KCS.
7.Bi a se le yo owo ta fipamo?
Ti awọn eyan ba fẹ yo KCS ti a fipamo, wọn nilo lati pe ọna atiyo ti adehun awon alafowosi si yiyo iye ta fipamo. Lẹyin ti bulooki 86,400 bati w ani sise (ojo meta), pe ọna yiyọ kuro ti adehun awọn alafọwọsi lati gba KCS ti a fipamo pada.
8.Ona di nigba lilo MetaMask (pẹlu ṣugbọn ki ṣe opin si didi ifiranse tabi idaduro, iṣoro ti ifihan alaye, abbl.)
Lo puloogi inu lati ṣafihan ni iboju to kun, eyiti o le duroṣinṣin diẹ tabi yan “Kiakia” lati fikun gaslimt ati gasPrice.
9.Bi o ṣe le lo afara KCC fun iyipada ohun-ini irekọja?
O le lo wo fidio ikẹkọ wa:https://www.youtube.com/watch?v=kZdX1V2Tgnc
Fun awọn olukọni diẹ sii, jọwọ ṣe alabapin si ikanni Youtube wa:https://www.youtube.com/channel/UCZhWm40SuAApnLqqq3F9o1w
10.Kini yio ṣẹlẹ ti a ba lo KCC dipo ERC20 nigbato a ba fi Tether ranse si adirẹsi ti ko ṣe atilẹyin KCC? Ṣe o ma pada sẹhin lẹhin akoko die?
Ti adiresi naa ba naa jẹ adirẹsi ti ara ẹni rẹ, isẹ naa rọrun pupọ. Yi nẹtiwọọki apamọwọafefe re pada si KCC, ki o si gbe adirẹsi rẹ wole ati adirẹsi adehun KCC-USDT rẹ, lẹhinna o le rii iye USDT re toku.
Ti adiresi naa ba jẹ ti paṣipaaro tabi apamọwọafefe ti ijoba, o nilo lati kan si atilẹyin onibara wọn lati jẹ ki wọn ṣe atilẹyin KCC tabi da wọn pada si adirẹsi rẹ.
Nitorinaa, a daba pe ki awọn eyan wa mo idi to fi fe firanse nitoripe awon ohun elo bulookichaini kose pare, eyi tunmo si pe ifiranse eyikeyi kose yi pada ti aba ti fi ranse, ati pe a n ma ro awon eyan ki won koko fi iye die ranse ko fi wo bo selo.
Lo ẹrọ aṣawakiri Chrome ṣi MetaMask extension site
Tẹle agbekale naa, ṣẹda apamọwọ ETH rẹ,toju kokoro ikọkọ rẹ tabi mnemonic;
Ṣe atunto Mainneti KCC
(1) Ṣi MetaMask, o le wo atunto to bawa【Ethereum mainneti】。
te【Ethereum mainneti】,te【asa RPC】lori akojọ aṣayan to si sile
(2) Fọwọsi iye iṣeto naa lati yipada si Mainneti KCC:
Orukọ Nẹtiwọọki:KCC-MAINNET
Ayelujara RPC tuntun:https://rpc-mainnet.kcc.network
Idanimọ Chaini: 321
Aami Owo (ki se dandan):KCS
Oluwakiri Ayelujara Bulooki (ki se dandan):https://explorer.kcc.io/en
Oti Se
[Fidio]Bii o ṣe le Mu Awọn Iṣowo to di la lori MetaMask (KCC)
[Fidio] Bii o ṣe le fi tokini miiran si apamọwọ MetaMask rẹ (KCC)